Ìṣe Àwọn Aposteli 10:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mọ̀ nípa Jesu ará Nasarẹti, bí Ọlọrun ti ṣe yàn án, tí ó fún un ní Ẹ̀mí Mímọ́ ati agbára; bí ó ti ṣe ń lọ káàkiri tí ó ń ṣe rere, tí ó ń wo gbogbo àwọn tí Satani ti ń dá lóró sàn, nítorí Ọlọrun wà pẹlu rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:29-46