Ìṣe Àwọn Aposteli 10:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùfọkànsìn ni. Òun ati gbogbo ìdílé rẹ̀ sì bẹ̀rù Ọlọrun. A máa ṣàánú àwọn eniyan lọpọlọpọ, a sì máa gbadura sí Ọlọrun nígbà gbogbo.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1-12