Ìṣe Àwọn Aposteli 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, ní nǹkan agogo mẹta ọ̀sán, ó rí ìran kan. Angẹli Ọlọrun wọlé tọ̀ ọ́ wá, ó ní, “Kọniliu!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1-8