Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà ní Kesaria tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Kọniliu. Ó jẹ́ balogun ọ̀rún ti ẹgbẹ́ tí à ń pè ní Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Itali.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1-6