Ìṣe Àwọn Aposteli 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan tí gbogbo wọn péjọ, wọ́n bi í pé, “Oluwa, ṣé àkókò tó nisinsinyii tí ìwọ yóo gba ìjọba pada fún Israẹli?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:1-12