Ìṣe Àwọn Aposteli 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí omi ni Johanu fi ń ṣe ìwẹ̀mọ́, ṣugbọn Ẹ̀mí Mímọ́ ni a óo fi ṣe ìwẹ̀mọ́ fun yín láìpẹ́ jọjọ.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:2-7