Ìṣe Àwọn Aposteli 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá wọn lóhùn pé, “Kì í ṣe tiyín láti mọ àkókò tabi ìgbà tí Baba ti fi sí ìkáwọ́ ara rẹ̀ nìkan ṣoṣo.

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:1-10