Ìṣe Àwọn Aposteli 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti tẹjú mọ́ òkè bí ó ti ń lọ, àwọn ọkunrin meji tí wọ́n wọ aṣọ funfun dúró tì wọ́n.

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:1-16