Ìṣe Àwọn Aposteli 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ní, “Ẹ̀yin ará Galili, kí ló dé tí ẹ fi dúró tí ẹ̀ ń wòkè bẹ́ẹ̀? Jesu kan náà, tí a mú kúrò lọ́dọ̀ yín, lọ sí ọ̀run yìí, yóo tún pada wá bí ẹ ṣe rí i tí ó ń lọ sí ọ̀run.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:5-14