Ìṣe Àwọn Aposteli 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, bí wọ́n ti ń wò ó, a gbé e sókè, ìkùukùu bò ó, wọn kò sì rí i mọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:1-11