Hosia 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni èmi ni mo kọ́ Efuraimu ní ìrìn,mo gbé wọn lé ọwọ́ mi,ṣugbọn wọn kò mọ̀ pé èmi ni mo wo àwọn sàn.

Hosia 11

Hosia 11:1-7