Hosia 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fà wọ́n mọ́ra pẹlu okùn àánú ati ìdè ìfẹ́,mo dàbí ẹni tí ó tú àjàgà kúrò ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ wọn,mo sì bẹ̀rẹ̀, mo gbé oúnjẹ kalẹ̀ níwájú wọn.

Hosia 11

Hosia 11:1-9