Hosia 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí mo ti ń pè wọ́n tó,bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń sá fún mi,wọ́n ń rúbọ sí àwọn oriṣa Baali,wọ́n ń sun turari sí ère.

Hosia 11

Hosia 11:1-11