Hosia 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọde, mo fẹ́ràn rẹ̀,láti ilẹ̀ Ijipti ni mo sì ti pe ọmọ mi jáde.

Hosia 11

Hosia 11:1-6