Ẹkún Jeremaya 4:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Ẹ máa yọ̀, kí inú yín sì máa dùn, ẹ̀yin ará Edomu,tí ń gbé ilẹ̀ Usi.Ṣugbọn ife náà yóo kọjá lọ́dọ̀ yín,ẹ óo mu ún ní àmuyó,ẹ óo sì tú ara yín síhòòhò.

22. Ẹ ti jìyà ẹ̀ṣẹ̀ yín ní àjẹpé,ẹ̀yin ará Sioni,OLUWA kò ní fi yín sílẹ̀ ní ìgbèkùn mọ́.Ṣugbọn yóo jẹ ẹ̀yin ará Edomu níyà fún ẹ̀ṣẹ̀ yín,yóo tú àṣírí ẹ̀ṣẹ̀ yín.

Ẹkún Jeremaya 4