Ẹkún Jeremaya 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ti jìyà ẹ̀ṣẹ̀ yín ní àjẹpé,ẹ̀yin ará Sioni,OLUWA kò ní fi yín sílẹ̀ ní ìgbèkùn mọ́.Ṣugbọn yóo jẹ ẹ̀yin ará Edomu níyà fún ẹ̀ṣẹ̀ yín,yóo tú àṣírí ẹ̀ṣẹ̀ yín.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:21-22