Ẹkún Jeremaya 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa yọ̀, kí inú yín sì máa dùn, ẹ̀yin ará Edomu,tí ń gbé ilẹ̀ Usi.Ṣugbọn ife náà yóo kọjá lọ́dọ̀ yín,ẹ óo mu ún ní àmuyó,ẹ óo sì tú ara yín síhòòhò.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:18-22