Ẹkún Jeremaya 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń káàkiri bí afọ́jú láàrin ìgboro,ẹ̀jẹ̀ àwọn tí wọ́n pa sọ wọ́n di aláìmọ́tóbẹ́ẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò lè fọwọ́ kan aṣọ wọn.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:4-20