Ẹkún Jeremaya 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wolii rẹ̀ ló fa èyí,ati àìdára àwọn alufaa rẹ̀,tí wọ́n pa olódodo láàrin ìlú.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:12-15