Ẹkún Jeremaya 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ranti gbogbo ìwà ibi wọn,kí o sì jẹ wọ́n níyà;bí o ti jẹ mí níyà,nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi.Ìrora mi pọ̀ ọkàn mi sì rẹ̀wẹ̀sì.”

Ẹkún Jeremaya 1

Ẹkún Jeremaya 1:16-22