Ẹkún Jeremaya 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò bí OLUWA ti fi ibinufi ìkùukùu bo Sioni mọ́lẹ̀.Ó ti wọ́ ògo Israẹli luláti òkè ọ̀run sórí ilẹ̀ ayé;kò tilẹ̀ ranti àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ ibinu rẹ̀.

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:1-4