Ẹkisodu 15:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Miriamu bá dá orin fún wọn pé,“Ẹ kọrin sí OLUWA,nítorí tí ó ti ja àjàṣẹ́gun tí ó lógo,ó ti da ati ẹṣin ati àwọn ẹlẹ́ṣin sinu Òkun Pupa.”

Ẹkisodu 15

Ẹkisodu 15:12-25