Ẹkisodu 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Miriamu, wolii obinrin, tíí ṣe arabinrin Aaroni, gbé ìlù timbireli lọ́wọ́, gbogbo àwọn obinrin sì tẹ̀lé e, wọ́n ń lu timbireli, wọ́n sì ń jó.

Ẹkisodu 15

Ẹkisodu 15:10-26