Ẹkisodu 15:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá bẹ̀rẹ̀ sí kó àwọn ọmọ Israẹli tẹ̀síwájú láti ibi Òkun Pupa, wọ́n ń lọ sí aṣálẹ̀ Ṣuri, ọjọ́ mẹta ni wọ́n fi rìn ninu aṣálẹ̀ láìrí omi.

Ẹkisodu 15

Ẹkisodu 15:17-24