Diutaronomi 6:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa pàápàá fi ojú wa rí i bí OLUWA ti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu ńlá tí wọ́n bani lẹ́rù sí àwọn ará Ijipti ati sí Farao ọba wọn, ati gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀.

Diutaronomi 6

Diutaronomi 6:13-23