Diutaronomi 6:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo dá wọn lóhùn pé, ‘A ti jẹ́ ẹrú Farao ní ilẹ̀ Ijipti rí, ṣugbọn agbára ni OLUWA fi kó wa jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti.

Diutaronomi 6

Diutaronomi 6:17-25