Diutaronomi 6:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí àwọn ọmọ yín bá bèèrè lọ́jọ́ iwájú pé, kí ni ìtumọ̀ àwọn ẹ̀rí ati ìlànà ati òfin tí OLUWA pa láṣẹ fun yín.

Diutaronomi 6

Diutaronomi 6:14-25