Diutaronomi 6:23 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sì kó wa jáde, kí ó lè kó wa wá sí orí ilẹ̀ tí ó ti búra láti fi fún àwọn baba wa.

Diutaronomi 6

Diutaronomi 6:22-25