Diutaronomi 29:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo yín pátá ni ẹ dúró níwájú OLUWA Ọlọrun yín lónìí, ati gbogbo àwọn olórí ninu àwọn ẹ̀yà yín, ati àwọn àgbààgbà ati àwọn olóyè ati àwọn ọkunrin Israẹli.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:4-12