Diutaronomi 29:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra yín, kí ẹ máa tẹ̀lé majẹmu yìí, kí ohun gbogbo tí ẹ bá dáwọ́lé lè máa yọrí sí rere.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:1-10