Diutaronomi 29:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ yín, àwọn aya yín, ati àwọn àlejò tí wọn ń gbé orí ilẹ̀ yín; àwọn tí wọn ń wá igi fun yín, ati àwọn tí wọn ń pọnmi fun yín.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:8-20