Diutaronomi 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wolii tí ó bá fi orúkọ mi jẹ́ iṣẹ́ tí n kò rán an, tabi tí ó jẹ́ iṣẹ́ kan fun yín ní orúkọ àwọn oriṣa, wolii náà gbọdọ̀ kú ni.’

Diutaronomi 18

Diutaronomi 18:19-22