Diutaronomi 18:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹ bá ń rò ninu ọkàn yín pé, báwo ni ẹ óo ti ṣe mọ ìgbà tí wolii kan bá ń jẹ́ iṣẹ́ tí Ọlọrun kò rán an.

Diutaronomi 18

Diutaronomi 18:16-22