Diutaronomi 18:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí kò bá gba ọ̀rọ̀ mi, tí yóo máa sọ ní orúkọ mi, èmi fúnra mi ni n óo jẹ olúwarẹ̀ níyà.

Diutaronomi 18

Diutaronomi 18:17-21