Diutaronomi 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun yín; ẹ sìn ín, kí ẹ sì súnmọ́ ọn. Orúkọ rẹ̀ ni kí ẹ máa fi búra.

Diutaronomi 10

Diutaronomi 10:14-22