Diutaronomi 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni kí ẹ máa yìn, òun ni Ọlọrun yín, tí ó ṣe nǹkan ńláńlá tí ó bani lẹ́rù wọnyi fun yín, tí ẹ̀yin náà sì fi ojú ara yín rí i.

Diutaronomi 10

Diutaronomi 10:14-22