Àwọn Ọba Kinni 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

n óo mú àwọn ọmọ Israẹli kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn, n óo sì kọ ilé ìsìn tí mo ti yà sí mímọ́ fún orúkọ mi sílẹ̀. Gbogbo ọmọ Israẹli yóo di ẹni àmúpòwe ati ẹlẹ́yà láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù.

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:1-11