Àwọn Ọba Kinni 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilé yìí yóo di òkìtì àlàpà, yóo sì di ohun àwòyanu ati ẹ̀gàn fún gbogbo ẹni tí ó bá ń rékọjá lọ. Wọn óo máa bi ara wọn léèrè pé, ‘Kí ló dé tí OLUWA fi ṣe báyìí sí ilẹ̀ yìí ati ilé yìí?’

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:6-18