Àwọn Ọba Kinni 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ìwọ tabi arọmọdọmọ rẹ bá yapa kúrò lẹ́yìn mi, tí ẹ bá ṣe àìgbọràn sí àwọn òfin ati ìlànà tí mo fi lélẹ̀ fún yín, tí ẹ bẹ̀rẹ̀ sí bọ oriṣa,

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:1-14