Àwọn Ọba Kinni 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

n óo fìdí ìjọba rẹ múlẹ̀ ní Israẹli, gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣèlérí fún Dafidi, baba rẹ, pé arọmọdọmọ rẹ̀ ni yóo máa jọba lórí àwọn ọmọ Israẹli títí lae.

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:1-15