Àwọn Ọba Kinni 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá sìn mí tọkàntọkàn pẹlu òtítọ́ inú, gẹ́gẹ́ bí Dafidi, baba rẹ, ti ṣe, bí o bá ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ, tí o sì pa òfin ati ìlànà mi mọ́,

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:1-12