Àwọn Ọba Kinni 8:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan rẹ sá ni wọ́n, ìwọ ni o sì ni wọ́n, ìwọ ni o kó wọn jáde láti ilẹ̀ Ijipti, ilẹ̀ tí ó gbóná janjan bí iná ìléru.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:46-60