Àwọn Ọba Kinni 8:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n, ati gbogbo àìdára tí wọ́n ṣe, kí o sì jẹ́ kí àwọn tí wọ́n kó wọn lẹ́rú ṣàánú wọn.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:49-54