Àwọn Ọba Kinni 8:52 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA Ọlọrun, fi ojurere wo àwa iranṣẹ rẹ, àní àwọn ọmọ Israẹli, eniyan rẹ, kí o sì gbọ́ adura ati ẹ̀bẹ̀ wọn nígbàkúùgbà tí wọ́n bá ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:51-61