Àwọn Ọba Kinni 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì rọ ọpọ́n bàbà meji, ó gbé wọn ka orí àwọn òpó náà. Gíga àwọn ọpọ́n náà jẹ́ igbọnwọ marun-un marun-un.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:8-19