Àwọn Ọba Kinni 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi bàbà ṣe òpó meji; gíga ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ igbọnwọ mejidinlogun, àyíká rẹ̀ sì jẹ́ igbọnwọ mejila, ó ní ihò ninu, nínípọn rẹ̀ sì jẹ́ ìka mẹrin. Bákan náà ni òpó keji.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:11-17