Àwọn Ọba Kinni 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi irin hun àwọ̀n meji fún àwọn ọpọ́n orí mejeeji tí wọ́n wà lórí àwọn òpó náà, àwọ̀n kọ̀ọ̀kan fún ọpọ́n orí òpó kọ̀ọ̀kan.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:9-18