Àwọn Ọba Kinni 22:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹtadinlogun tí Jehoṣafati, ọba Juda, gun orí oyè ni Ahasaya, ọmọ Ahabu, gun orí oyè ní ilẹ̀ Israẹli, ó sì jọba ní Samaria fún ọdún meji.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:50-53