Àwọn Ọba Kinni 22:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Jehoṣafati kú, wọ́n sì sin ín sí ibojì àwọn ọba, ní ìlú Dafidi, baba ńlá rẹ̀. Jehoramu ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè dípò rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:40-53