Àwọn Ọba Kinni 22:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasaya ọba Israẹli, ọmọ Ahabu, ọba Israẹli sọ fún Jehoṣafati pé kí àwọn eniyan òun bá àwọn eniyan rẹ̀ tu ọkọ̀ lọ, ṣugbọn Jehoṣafati kò gbà.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:39-50